Bibeli fun awon omode. Ajinde akoko

Similar documents
Omo Elomiran. Ipolongo Ibanisobi Omo ti Aladani Jakejado Orile Ede. Isalaye ibanisobi omo ti aladanii. Awon ifilele ofin fun olutoju fun ibanisobi omo

1.- L a m e j o r o p c ió n e s c l o na r e l d i s co ( s e e x p li c a r á d es p u é s ).

Campus Sustainability Assessment and Related Literature

1. Oblast rozvoj spolků a SU UK 1.1. Zvyšování kvalifikace Školení Zapojení do projektů Poradenství 1.2. Financování

SCO TT G LEA SO N D EM O Z G EB R E-

BLADE 12th Generation. Rafał Olszewski. Łukasz Matras

L a h ip e r t e n s ió n a r t e r ia l s e d e f in e c o m o u n n iv e l d e p r e s ió n a r t e r ia l s is t ó lic a ( P A S ) m a y o r o

H ig h L e v e l O v e r v iew. S te p h a n M a rt in. S e n io r S y s te m A rc h i te ct

How To Translate English To Yoruba Language To Yoranuva


i n g S e c u r it y 3 1B# ; u r w e b a p p li c a tio n s f r o m ha c ke r s w ith t his å ] í d : L : g u id e Scanned by CamScanner

JCUT-3030/6090/1212/1218/1325/1530

Improving Text Entry Performance for Spanish-Speaking Non-Expert and Impaired Users

Put the human back in Human Resources.

Using Predictive Modeling to Reduce Claims Losses in Auto Physical Damage

Odi (Idi) Meji. Ogbe - the open road, birth. Oyeku - end of cycle, death. Iwori - consciousness, transformation. Odi - reincarnation, re-birth

S e w i n g m a c h i n e s for but t - seams. - c o m p l e t e b r o c h u r e -


I n la n d N a v ig a t io n a co n t r ib u t io n t o eco n o m y su st a i n a b i l i t y



Online Department Stores. What are we searching for?


Opis przedmiotu zamówienia - zakres czynności Usługi sprzątania obiektów Gdyńskiego Centrum Sportu

Chem 115 POGIL Worksheet - Week 4 Moles & Stoichiometry Answers

»The World Thinkers' Panel on the Sustainable Future of Humankind«D E C L A R A T I O N

B I N G O B I N G O. Hf Cd Na Nb Lr. I Fl Fr Mo Si. Ho Bi Ce Eu Ac. Md Co P Pa Tc. Uut Rh K N. Sb At Md H. Bh Cm H Bi Es. Mo Uus Lu P F.


8698 Van hati e 1 2, p er us kor jaus ja muut os pδivδkot itiloiksi. Ur akkat ar jousten avauspφyt δkir ja

P R E F E I T U R A M U N I C I P A L D E J A R D I M

Bible for Children. presents RUTH: A LOVE STORY

SOCIO-CULTURAL FACTORS AFFECTING PREGNANCY OUTCOME AMONG THE OGU SPEAKING PEOPLE OF BADAGRY AREA OF LAGOS STATE, NIGERIA.

SAMSON, GOD S STRONG MAN

R e t r o f i t o f t C i r u n i s g e C o n t r o l

Frederikshavn kommunale skolevæsen

With Rejoicing Hearts/ Con Amor Jovial. A Fm7 B sus 4 B Cm Cm7/B

CLASS TEST GRADE 11. PHYSICAL SCIENCES: CHEMISTRY Test 6: Chemical change

MAX. IP Conferencing Phone

Chem 115 POGIL Worksheet - Week 4 Moles & Stoichiometry

All answers must use the correct number of significant figures, and must show units!

CREATE SHAPE VISUALIZE

Mitel 5000 Communications Platform

Bible for Children. presents THE FIRST EASTER

U S B Pay m e n t P r o c e s s i n g TM

B a rn e y W a r f. U r b a n S tu d ie s, V o l. 3 2, N o. 2, ±3 7 8



Denesu łıne Honıe. PAGC Education: Language & Culture. If the very old will remember, the very young will listen. ~ Chief Dan George

From Quantum to Matter 2006

MOTORI ELETTRICI TRIFASE SERIE MS MOTORI ELETTRICI MONOFASE SERIE MY

Electronegativity and Polarity

MITEL. Administrator Endpoint Guide

THE GIRL WHO LIVED TWICE

Như ng kiê n thư c câ n biê t vê giâ y phe p cư tru điê n tư (eat)

Endomines - Ilomantsi Gold Project


CHARLIE S CHALLENGE: At Home Invention Kit

Nearer, My God, to Thee

The Results of Implementing an ESL Orientation Class

BIOBANK LPCE-NICE CHEST

ELECTRON CONFIGURATION (SHORT FORM) # of electrons in the subshell. valence electrons Valence electrons have the largest value for "n"!

Present. and. RFA No79/2OO5

d e f i n i c j i p o s t a w y, z w i z a n e j e s t t o m. i n. z t y m, i p o jі c i e t o

Issue 1, Volume 1 January news for the residents of alamo heights SAN ANTONIO STOCK SHOW & RODEO. T h e S a n Antonio Stock Show & Rodeo

MBU-1000 & 2000 Supported Phone Features

اocukluk اa nda Beslenme


UFPA Brazil. d e R e d e s Ó p tic a s e s e u s Im p a c to s n o F u tu r o d a In te r n e t


Overview of Spellings on


OpenScape Office V3 interaction with Microsoft Small Business Server 2011 Standard

Scholarship Help for Technology Students

E S T A D O D O C E A R Á P R E F E I T U R A M U N I C I P A L D E C R U Z C Â M A R A M U N I C I P A L D E C R U Z

Tuition Reimbursement Program. Handbook

Children s Books in Chinese, French, Italian and Japanese Languages Joyner Library s Teaching Resources Center A Selective Bibliography

How To Rate Plan On A Credit Card With A Credit Union


MODERN ATOMIC THEORY AND THE PERIODIC TABLE


C + + a G iriş 2. K o n tro l y a p ıla rı if/e ls e b re a k co n tin u e g o to sw itc h D ö n g ü le r w h ile d o -w h ile fo r

UNIK4250 Security in Distributed Systems University of Oslo Spring Part 7 Wireless Network Security

Sustainable energy products Simulation based design for recycling

Vom prozessorientierten Wissensmanagement zum intelligenten Engineering-Portal

He Will Hold Me Fast (When I Fear My Faith Will Fail)

az évi L X V. tv á ra figyelem m el 20. sz á m ú UTASÍTÁSA B u d a p e s t, é v i jú liu s hó 2 8 -á n.

Bible for Children. presents JOSHUA TAKES CHARGE


Middagserie Eschatologie Oosterparkkerk, Amsterdam, December 2007

Learn Unifon Spell the Sounds!


ON YOUR TURN: ROLLING AND MOVING

You shouldn t use investments for savings or short term goals/expenses because of two primary reasons:

2.590Ђ 240Ђ 89Ђ 380Ђ 125Ђ 550Ђ 230Ђ 499Ђ 650Ђ 170Ђ 295Ђ ZONA NOTTE 1.650Ђ Ђ 175 Ђ Ђ 380 Ђ 740 Ђ 115

M a rie - Claire V la a m s, B ra b a nt s, Achte rh o e k s e n ve l e imit atie s.

Transcription:

Bibeli fun awon omode Ajinde akoko

Ikosile gba owo: Edward Hughes Ayaworan: Janie Forest Olu lo: Lyn Doerksen Atunmo ede: Oluwashina Oluwadimu Alakoso: Bible for Children www.m1914.org 2013 Bible for Children, Inc. Iwe ase: Oni ase lati se atunko tabi attune itan yi, niwon igba ti o ko so di owo.

Arabinrin na duro si eti apata na, oju ekun re nwo iran buburu na. omo re nku lo. Iya na ni Maria, osi duro leti ibiti akan Jesu mo agbelebu.

Bawo li gbogbo eyi se bere? Bawo li Jesu se maa pari aye didara si aye itiju ni? Bawo li Olorun se maa fi omo re sile lati ku sori igi agbelebu? Se Jesu o mo eniti ohun je ni? Tabi Olorun kose dada ni?

Rara o! Olorun se dada. Jesu ko se asise. Jesu mo wipe a o pa ohun gba owo awon eni ibi. Nigbati Jesu wa ni omode, Simeoni arugbo ti so fun Maria ohun ibi to nbo wa sele.

Ojo die ki ato pa Jesu, arabinrin kan wa lati wa da ororo iyebiye si ese Jesu. O n da owo nu awon omo ehin re wi. Oti se ise rere Jesu wi bayi. O se eyi fun isinku mi. Iru oro kayefi wo re!

Lehin eyi, Judasi, okan ninu omo ehin mejila, gba lati fi Jesu han fun awon alufa agba pelu ogbon wura.

Li ajo irekoja awon Ju, Jesu je ounje igbehin pelu awon omo ehin re. o so ohun iyanu fun won nipa Olorun ati awon ileri re si awon to feran re. Jesu si fi akara ati omi fun won lati pin. Eyi ni lati ran won leti wipe Jesu fi ara ati eje re fun wa fun idariji ese.

Jesu si so fun awon omo ehin re wipe a o fi ohun han awon omo ehin re yio si fonka. Emi ko ni salo, Peteru wi bayi. Ki akuko to ke, iwo yio komi sile leemeta, Jesu wi.

Li oru ojo na, Jesu lo lati gbadura ninu ogba Getsimani. Awon omo ehin re ti owa lodo re sun lo fonfon. Baba a mi, Jesu gbadura, Jeki ago yi re koja lori mi, sugbon kiise bi mo tife, Ife re ni ko se.

Lojiji, opo ero wonu ogba, Judasi lo siwaju won. Jesu ko ja, sugbon Peteru ge eti okunrin kan sile. Lai pariwo, Jesu fi owo kan eti arakunrin na osi wo san. Jesu mo wipe ki amu ohun pelu ife olorun fun ohun.

Awon eyi mu Jesu lo si ile Alufa agba. Nibe, awon agba Ju so wipe ki Jesu ku. Nitosi, Peteru duro leba ina awon eru osi nworan.

Leemeta li awon eniyan wo Peteru won si wipe Iwo wa pelu Jesu! Leemeta Peteru ko eyi, gegbi Jesu se wi. Peteru gegun o si bura.

Gele, akuko ke. O dabi ohun Olorun si Peteru. O ranti oro Jesu, Peteru sonkun kikoro.

Judasi pelu bara je. O mo wipe Jesu ko jebi ese Kankan. Judasi gbe ogbon wura pada sugbon awon alufa ki yio gba.

Judasi so owo na sile, o jade lo o si pokun so.

Awon alufa mu Jesu to Pilatu wa, Gomina Romu. Pilatu so wipe, Emi ko ri ese kan pelu okunrin yi. Sugbon awon eniyan gbogbo wipe, Kan mo agbelebu! Kan mo agbelebu!

Nigbeyin, Pilatu gbo, osi pase ki akan Jesu mo igi agbelebu. Awon Omo-ogun gba Jesu lese, tu ito si loju, won si naa legba. Won de ade egun lee lori. Won si kan mo igi agbelebu lati ku.

Jesu mo wipe ohun yio ku iku oro yi. O si mo wipe iku re yio mu idariji ese wa fun awon to gbekele ohun. Ole meji li akan pelu Jesu. Okan gbagbo o losi paradise. Ekeji ko gbagbo.

Lehin ijiya pipe, Jesu wipe o ti pari, o si ku. Ise re ti pari. Awon ore re sin sinu isa oku titun.

Awon omo-ogun Romu so ibi iboji. Kosi eniti o le wole - tabi jade.

Bi eyi ba je opin itan yi, iba mu are wa. Sugbon Olorun se ohun ara kan. Jesu ko ku!

Li kutukutu owuro ojo akoko ninu ose, awon omolehin Jesu kan ri iboji wipe osi sile. Nigbati won wo inu re, Jesu kosi nibe.

Arabinrin kan lo duro, o sonkun li iboji. Jesu farahan! O sare loso fun awon omo ehin toku. JESU WA LAAYE! JESU TI PADA WA LATI ISA OKU!

Laipe, Jesu pada waba awon omo ehin re, o si fi owo re han won. Otito ni. JESU WA LAAYE SI! O DARIJI Peteru ti o ko sile, o si wi fun awon omo ehin re ki won so fun gbogbo eniyan nipa ohun. O si pada losi orun ti oti wa nigba keresimesi akoko.

Ajinde akoko Itan lati inu oro Olorun, Bibeli lari ka ninu Iwe Matthew 26-28, Luku 22-24, Johannu 13-21 Iwole oro re funwa ni imole. Orin Dafidi 119:130

Opin

Itan Bibeli yii so fun wa nipa Olorun iyanu wa t oda wa ti osi fe ki amo ohun. Olorun mo wipe ati se ohun ibi, ti ope ni ese. Iku ni ere ese, sugbon Olorun feran re tobe ge tofi omo re kan soso, Jesu, ranse lati ku lori igi agbelebu ki osi jiya fun ese re. Jesu si pada wa si aaye osi losi ile l orun! Bi o ba gbagbo ninu Jesu ti osi toro idariji ese re, Yi o se eyi! Yi o si wa gbe ninu re nisisiyi, iwo yio si gbe pelu re lailai. Bi o ba gbagbo wipe otito ni eyi, so fun Olorun wipe: Jesu mi owon, Mo gbagbo wipe ire ni Olorun, o di eniyan lati ku fun ese mi, osi wa laaye sibe. Jowo wa sinu aye mi ki osi dari ese mi jimi, ki emi ki oni aye otun nisisiyi, ati ni ojo kan ki emi kole wa pelu re titi lai. Ranmilowo lati gbo tire ati lati je omo o re. Amin. Ka Bibeli re ki osi ba Olorun soro lojumo! Johannu ori keta ese kerindinlogun.